Quran with Yoruba translation - Surah Al-Waqi‘ah ayat 8 - الوَاقِعة - Page - Juz 27
﴿فَأَصۡحَٰبُ ٱلۡمَيۡمَنَةِ مَآ أَصۡحَٰبُ ٱلۡمَيۡمَنَةِ ﴾
[الوَاقِعة: 8]
﴿فأصحاب الميمنة ما أصحاب الميمنة﴾ [الوَاقِعة: 8]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni ìjọ òsì àti ìjọ aṣíwájú. Àmọ́ nínú sūrah al-Balad; 90:18-19 àti sūrah az-Zalzalah; 99:6-8 Allāhu (subhānahu wa ta'ālā) pín wọn sí ìjọ méjì. Ìjọ méjì kúkú ni gbogbo ẹ̀dá ní ọ̀run 8 Àwọn èrò ọwọ́ ọ̀tún, kí ni (ó máa ti dára tó fún) àwọn èrò ọwọ́ ọ̀tún |