Quran with Yoruba translation - Surah Al-hadid ayat 5 - الحدِيد - Page - Juz 27
﴿لَّهُۥ مُلۡكُ ٱلسَّمَٰوَٰتِ وَٱلۡأَرۡضِۚ وَإِلَى ٱللَّهِ تُرۡجَعُ ٱلۡأُمُورُ ﴾
[الحدِيد: 5]
﴿له ملك السموات والأرض وإلى الله ترجع الأمور﴾ [الحدِيد: 5]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni TiRẹ̀ ni ìjọba àwọn sánmọ̀ àti ilẹ̀. Ọ̀dọ̀ Allāhu sì ni wọ́n máa ṣẹ́rí àwọn ọ̀rọ̀ ẹ̀dá padà sí |