Quran with Yoruba translation - Surah Al-An‘am ayat 106 - الأنعَام - Page - Juz 7
﴿ٱتَّبِعۡ مَآ أُوحِيَ إِلَيۡكَ مِن رَّبِّكَۖ لَآ إِلَٰهَ إِلَّا هُوَۖ وَأَعۡرِضۡ عَنِ ٱلۡمُشۡرِكِينَ ﴾
[الأنعَام: 106]
﴿اتبع ما أوحي إليك من ربك لا إله إلا هو وأعرض عن﴾ [الأنعَام: 106]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Tẹ̀lé ohun tí wọ́n fi rán ọ́ ní ìmísí láti ọ̀dọ̀ Olúwa rẹ. Kò sí ẹni tí ìjọ́sìn tọ́ sí àfi Òun. Kí o sì ṣẹ́rí kúrò ní ọ̀dọ̀ àwọn ọ̀ṣẹbọ |