Quran with Yoruba translation - Surah Al-An‘am ayat 105 - الأنعَام - Page - Juz 7
﴿وَكَذَٰلِكَ نُصَرِّفُ ٱلۡأٓيَٰتِ وَلِيَقُولُواْ دَرَسۡتَ وَلِنُبَيِّنَهُۥ لِقَوۡمٖ يَعۡلَمُونَ ﴾
[الأنعَام: 105]
﴿وكذلك نصرف الآيات وليقولوا درست ولنبينه لقوم يعلمون﴾ [الأنعَام: 105]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Báyẹn ni A ṣe ń mú àwọn āyah wá lóníran-ànran ọ̀nà nítorí kí wọ́n lè wí pé: "O kẹ́kọ̀ọ́ (rẹ̀ lọ́dọ̀ àwọn ènìyàn ni." Dípò kí wọ́n wí pé: "Wọ́n sọ̀ ọ́ kalẹ̀ fún ọ ni." àti nítorí kí A lè ṣe àlàyé rẹ̀ fún àwọn ènìyàn t’ó nímọ̀) |