Quran with Yoruba translation - Surah Al-An‘am ayat 11 - الأنعَام - Page - Juz 7
﴿قُلۡ سِيرُواْ فِي ٱلۡأَرۡضِ ثُمَّ ٱنظُرُواْ كَيۡفَ كَانَ عَٰقِبَةُ ٱلۡمُكَذِّبِينَ ﴾
[الأنعَام: 11]
﴿قل سيروا في الأرض ثم انظروا كيف كان عاقبة المكذبين﴾ [الأنعَام: 11]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Sọ pé: “Ẹ rin orí ilẹ̀ lọ, lẹ́yìn náà kí ẹ wo báwo ni àtubọ̀tán àwọn t’ó ń pe òdodo nírọ́ ṣe rí.” |