Quran with Yoruba translation - Surah Al-An‘am ayat 155 - الأنعَام - Page - Juz 8
﴿وَهَٰذَا كِتَٰبٌ أَنزَلۡنَٰهُ مُبَارَكٞ فَٱتَّبِعُوهُ وَٱتَّقُواْ لَعَلَّكُمۡ تُرۡحَمُونَ ﴾
[الأنعَام: 155]
﴿وهذا كتاب أنـزلناه مبارك فاتبعوه واتقوا لعلكم ترحمون﴾ [الأنعَام: 155]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Èyí ni Tírà ìbùkún tí A sọ̀kalẹ̀. Nítorí náà, ẹ tẹ̀lé e. Kí ẹ sì bẹ̀rù (Allāhu) nítorí kí A lè kẹ yín |