×

Leyin naa, A fun (Anabi) Musa ni Tira ni pipe perepere fun 6:154 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Al-An‘am ⮕ (6:154) ayat 154 in Yoruba

6:154 Surah Al-An‘am ayat 154 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Al-An‘am ayat 154 - الأنعَام - Page - Juz 8

﴿ثُمَّ ءَاتَيۡنَا مُوسَى ٱلۡكِتَٰبَ تَمَامًا عَلَى ٱلَّذِيٓ أَحۡسَنَ وَتَفۡصِيلٗا لِّكُلِّ شَيۡءٖ وَهُدٗى وَرَحۡمَةٗ لَّعَلَّهُم بِلِقَآءِ رَبِّهِمۡ يُؤۡمِنُونَ ﴾
[الأنعَام: 154]

Leyin naa, A fun (Anabi) Musa ni Tira ni pipe perepere fun eni ti o maa se daadaa. (O je) alaye fun gbogbo nnkan. (O tun je) imona ati ike nitori ki won le ni igbagbo ninu ipade Oluwa won

❮ Previous Next ❯

ترجمة: ثم آتينا موسى الكتاب تماما على الذي أحسن وتفصيلا لكل شيء وهدى, باللغة اليوربا

﴿ثم آتينا موسى الكتاب تماما على الذي أحسن وتفصيلا لكل شيء وهدى﴾ [الأنعَام: 154]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Lẹ́yìn náà, A fún (Ànábì) Mūsā ní Tírà ní pípé pérépéré fún ẹni tí ó máa ṣe dáadáa. (Ó jẹ́) àlàyé fún gbogbo n̄ǹkan. (Ó tún jẹ́) ìmọ̀nà àti ìkẹ́ nítorí kí wọ́n lè ní ìgbàgbọ́ nínú ìpàdé Olúwa wọn
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek