Quran with Yoruba translation - Surah Al-An‘am ayat 45 - الأنعَام - Page - Juz 7
﴿فَقُطِعَ دَابِرُ ٱلۡقَوۡمِ ٱلَّذِينَ ظَلَمُواْۚ وَٱلۡحَمۡدُ لِلَّهِ رَبِّ ٱلۡعَٰلَمِينَ ﴾ 
[الأنعَام: 45]
﴿فقطع دابر القوم الذين ظلموا والحمد لله رب العالمين﴾ [الأنعَام: 45]
| Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nítorí náà, A pa ìjọ t’ó ṣàbòsí run pátápátá. Gbogbo ọpẹ́ sì ń jẹ́ ti Allāhu, Olúwa gbogbo ẹ̀dá  |