×

(Ise jije re tun wa fun) awon miiran ti won maa wa 62:3 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Al-Jumu‘ah ⮕ (62:3) ayat 3 in Yoruba

62:3 Surah Al-Jumu‘ah ayat 3 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Al-Jumu‘ah ayat 3 - الجُمعَة - Page - Juz 28

﴿وَءَاخَرِينَ مِنۡهُمۡ لَمَّا يَلۡحَقُواْ بِهِمۡۚ وَهُوَ ٱلۡعَزِيزُ ٱلۡحَكِيمُ ﴾
[الجُمعَة: 3]

(Ise jije re tun wa fun) awon miiran ti won maa wa ninu awon (omoleyin re), amo ti won ko ti i rin kan won. (Allahu) Oun ni Alagbara, Ologbon

❮ Previous Next ❯

ترجمة: وآخرين منهم لما يلحقوا بهم وهو العزيز الحكيم, باللغة اليوربا

﴿وآخرين منهم لما يلحقوا بهم وهو العزيز الحكيم﴾ [الجُمعَة: 3]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
(Iṣẹ́ jíjẹ́ rẹ̀ tún wà fún) àwọn mìíràn tí wọ́n máa wà nínú àwọn (ọmọlẹ́yìn rẹ̀), àmọ́ tí wọn kò tí ì rìn kàn wọ́n. (Allāhu) Òun ni Alágbára, Ọlọ́gbọ́n
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek