Quran with Yoruba translation - Surah At-Taghabun ayat 13 - التغَابُن - Page - Juz 28
﴿ٱللَّهُ لَآ إِلَٰهَ إِلَّا هُوَۚ وَعَلَى ٱللَّهِ فَلۡيَتَوَكَّلِ ٱلۡمُؤۡمِنُونَ ﴾
[التغَابُن: 13]
﴿الله لا إله إلا هو وعلى الله فليتوكل المؤمنون﴾ [التغَابُن: 13]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Allāhu, kò sí ọlọ́hun tí ìjọ́sìn tọ́ sí àfi Òun. Allāhu sì ni kí àwọn onígbàgbọ́ òdodo gbáralé |