×

Awon obinrin t’o ti soreti nu nipa nnkan osu sise ninu awon 65:4 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah AT-Talaq ⮕ (65:4) ayat 4 in Yoruba

65:4 Surah AT-Talaq ayat 4 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah AT-Talaq ayat 4 - الطَّلَاق - Page - Juz 28

﴿وَٱلَّٰٓـِٔي يَئِسۡنَ مِنَ ٱلۡمَحِيضِ مِن نِّسَآئِكُمۡ إِنِ ٱرۡتَبۡتُمۡ فَعِدَّتُهُنَّ ثَلَٰثَةُ أَشۡهُرٖ وَٱلَّٰٓـِٔي لَمۡ يَحِضۡنَۚ وَأُوْلَٰتُ ٱلۡأَحۡمَالِ أَجَلُهُنَّ أَن يَضَعۡنَ حَمۡلَهُنَّۚ وَمَن يَتَّقِ ٱللَّهَ يَجۡعَل لَّهُۥ مِنۡ أَمۡرِهِۦ يُسۡرٗا ﴾
[الطَّلَاق: 4]

Awon obinrin t’o ti soreti nu nipa nnkan osu sise ninu awon obinrin yin, ti e ba seyemeji, onka ojo ikosile won ni osu meta. (Bee naa ni fun) awon ti ko ti i maa se nnkan osu. Awon oloyun, ipari onka ojo opo ikosile tiwon ni pe ki won bi oyun inu won. Enikeni ti o ba n beru Allahu, O maa se oro re ni irorun

❮ Previous Next ❯

ترجمة: واللائي يئسن من المحيض من نسائكم إن ارتبتم فعدتهن ثلاثة أشهر واللائي, باللغة اليوربا

﴿واللائي يئسن من المحيض من نسائكم إن ارتبتم فعدتهن ثلاثة أشهر واللائي﴾ [الطَّلَاق: 4]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Àwọn obìnrin t’ó ti sọ̀rètí nù nípa n̄ǹkan oṣù ṣíṣe nínú àwọn obìnrin yín, tí ẹ bá ṣeyèméjì, òǹkà ọjọ́ ìkọ̀sílẹ̀ wọn ni oṣù mẹ́ta. (Bẹ́ẹ̀ náà ni fún) àwọn tí kò tí ì máa ṣe n̄ǹkan oṣù. Àwọn olóyún, ìparí òǹkà ọjọ́ opó ìkọ̀sílẹ̀ tiwọn ni pé kí wọ́n bí oyún inú wọn. Ẹnikẹ́ni tí ó bá ń bẹ̀rù Allāhu, Ó máa ṣe ọ̀rọ̀ rẹ̀ ní ìrọ̀rùn
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek