Quran with Yoruba translation - Surah Al-haqqah ayat 4 - الحَاقة - Page - Juz 29
﴿كَذَّبَتۡ ثَمُودُ وَعَادُۢ بِٱلۡقَارِعَةِ ﴾
[الحَاقة: 4]
﴿كذبت ثمود وعاد بالقارعة﴾ [الحَاقة: 4]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àwọn ìjọ Thamūd àti ìjọ ‘Ād pe Ìpáyà nírọ́ |