Quran with Yoruba translation - Surah Al-haqqah ayat 5 - الحَاقة - Page - Juz 29
﴿فَأَمَّا ثَمُودُ فَأُهۡلِكُواْ بِٱلطَّاغِيَةِ ﴾
[الحَاقة: 5]
﴿فأما ثمود فأهلكوا بالطاغية﴾ [الحَاقة: 5]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ní ti ìjọ Thamūd, wọ́n fi igbe t’ó tayọ ẹnu-àlà pa wọ́n rẹ́ |