Quran with Yoruba translation - Surah Al-A‘raf ayat 110 - الأعرَاف - Page - Juz 9
﴿يُرِيدُ أَن يُخۡرِجَكُم مِّنۡ أَرۡضِكُمۡۖ فَمَاذَا تَأۡمُرُونَ ﴾
[الأعرَاف: 110]
﴿يريد أن يخرجكم من أرضكم فماذا تأمرون﴾ [الأعرَاف: 110]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ó fẹ́ ko yín kúrò lórí ilẹ̀ yín ni." (Fir‘aon wí pé: ) “Kí ni ohun tí ẹ máa mú wá ní ìmọ̀ràn?” |