Quran with Yoruba translation - Surah Al-A‘raf ayat 111 - الأعرَاف - Page - Juz 9
﴿قَالُوٓاْ أَرۡجِهۡ وَأَخَاهُ وَأَرۡسِلۡ فِي ٱلۡمَدَآئِنِ حَٰشِرِينَ ﴾
[الأعرَاف: 111]
﴿قالوا أرجه وأخاه وأرسل في المدائن حاشرين﴾ [الأعرَاف: 111]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọ́n sì wí pé: "Dá òun àti arákùnrin rẹ̀ dúró ná, kí o sì rán àwọn akónijọ sí àwọn ìlú |