Quran with Yoruba translation - Surah Al-A‘raf ayat 114 - الأعرَاف - Page - Juz 9
﴿قَالَ نَعَمۡ وَإِنَّكُمۡ لَمِنَ ٱلۡمُقَرَّبِينَ ﴾
[الأعرَاف: 114]
﴿قال نعم وإنكم لمن المقربين﴾ [الأعرَاف: 114]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ó wí pé: “Bẹ́ẹ̀ ni. Àti pé dájúdájú ẹ̀yin gbọ́dọ̀ wà nínú àwọn alásùn-únmọ́ (mi).” |