Quran with Yoruba translation - Surah Al-A‘raf ayat 115 - الأعرَاف - Page - Juz 9
﴿قَالُواْ يَٰمُوسَىٰٓ إِمَّآ أَن تُلۡقِيَ وَإِمَّآ أَن نَّكُونَ نَحۡنُ ٱلۡمُلۡقِينَ ﴾
[الأعرَاف: 115]
﴿قالوا ياموسى إما أن تلقي وإما أن نكون نحن الملقين﴾ [الأعرَاف: 115]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Àwọn òpìdán) wí pé: “Mūsā, o máa (kọ́kọ́) ju ọ̀pá sílẹ̀ ni, tàbí àwa ni a máa (kọ́kọ́) jù ú sílẹ̀.” |