Quran with Yoruba translation - Surah Al-A‘raf ayat 125 - الأعرَاف - Page - Juz 9
﴿قَالُوٓاْ إِنَّآ إِلَىٰ رَبِّنَا مُنقَلِبُونَ ﴾
[الأعرَاف: 125]
﴿قالوا إنا إلى ربنا منقلبون﴾ [الأعرَاف: 125]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọ́n sọ pé: "Dájúdájú ọ̀dọ̀ Olúwa wa sì ni a máa fàbọ̀ sí |