×

Dajudaju awon ti e n pe leyin Allahu, eru bi iru yin 7:194 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Al-A‘raf ⮕ (7:194) ayat 194 in Yoruba

7:194 Surah Al-A‘raf ayat 194 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Al-A‘raf ayat 194 - الأعرَاف - Page - Juz 9

﴿إِنَّ ٱلَّذِينَ تَدۡعُونَ مِن دُونِ ٱللَّهِ عِبَادٌ أَمۡثَالُكُمۡۖ فَٱدۡعُوهُمۡ فَلۡيَسۡتَجِيبُواْ لَكُمۡ إِن كُنتُمۡ صَٰدِقِينَ ﴾
[الأعرَاف: 194]

Dajudaju awon ti e n pe leyin Allahu, eru bi iru yin ni won. Nitori naa, e pe won wo, ki won da yin lohun ti e ba je olododo

❮ Previous Next ❯

ترجمة: إن الذين تدعون من دون الله عباد أمثالكم فادعوهم فليستجيبوا لكم إن, باللغة اليوربا

﴿إن الذين تدعون من دون الله عباد أمثالكم فادعوهم فليستجيبوا لكم إن﴾ [الأعرَاف: 194]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Dájúdájú àwọn tí ẹ̀ ń pè lẹ́yìn Allāhu, ẹrú bí irú yin ni wọ́n. Nítorí náà, ẹ pè wọ́n wò, kí wọ́n da yín lóhùn tí ẹ bá jẹ́ olódodo
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek