Quran with Yoruba translation - Surah Al-Ma‘arij ayat 2 - المَعَارج - Page - Juz 29
﴿لِّلۡكَٰفِرِينَ لَيۡسَ لَهُۥ دَافِعٞ ﴾
[المَعَارج: 2]
﴿للكافرين ليس له دافع﴾ [المَعَارج: 2]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni sí àwọn aláìgbàgbọ́. Kò sì sí ẹni tí ó máa dí i lọ́wọ́ |