Quran with Yoruba translation - Surah An-Naba’ ayat 18 - النَّبَإ - Page - Juz 30
﴿يَوۡمَ يُنفَخُ فِي ٱلصُّورِ فَتَأۡتُونَ أَفۡوَاجٗا ﴾
[النَّبَإ: 18]
﴿يوم ينفخ في الصور فتأتون أفواجا﴾ [النَّبَإ: 18]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Ìyẹn ni) ọjọ́ tí wọ́n á fọn fèrè oníwo fún àjíǹde. Ẹ̀yin yó sì máa wá níjọ-níjọ |