Quran with Yoruba translation - Surah Al-Anfal ayat 14 - الأنفَال - Page - Juz 9
﴿ذَٰلِكُمۡ فَذُوقُوهُ وَأَنَّ لِلۡكَٰفِرِينَ عَذَابَ ٱلنَّارِ ﴾ 
[الأنفَال: 14]
﴿ذلكم فذوقوه وأن للكافرين عذاب النار﴾ [الأنفَال: 14]
| Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ìyẹn (nìyà tayé). Nítorí náà, ẹ tọ́ ọ wò. Àti pé dájúdájú ìyà Iná ń bẹ fún àwọn aláìgbàgbọ́ |