Quran with Yoruba translation - Surah Al-Anfal ayat 55 - الأنفَال - Page - Juz 10
﴿إِنَّ شَرَّ ٱلدَّوَآبِّ عِندَ ٱللَّهِ ٱلَّذِينَ كَفَرُواْ فَهُمۡ لَا يُؤۡمِنُونَ ﴾
[الأنفَال: 55]
﴿إن شر الدواب عند الله الذين كفروا فهم لا يؤمنون﴾ [الأنفَال: 55]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú ẹ̀dá abẹ̀mí t’ó burú jùlọ lọ́dọ̀ Allāhu ni àwọn t’ó ṣàì gbàgbọ́. Nítorí náà, wọn kò níí gbàgbọ́ |