Quran with Yoruba translation - Surah Al-Anfal ayat 64 - الأنفَال - Page - Juz 10
﴿يَٰٓأَيُّهَا ٱلنَّبِيُّ حَسۡبُكَ ٱللَّهُ وَمَنِ ٱتَّبَعَكَ مِنَ ٱلۡمُؤۡمِنِينَ ﴾
[الأنفَال: 64]
﴿ياأيها النبي حسبك الله ومن اتبعك من المؤمنين﴾ [الأنفَال: 64]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ìwọ Ànábì, Allāhu ti tó ìwọ àti àwọn t’ó tẹ̀lé ọ nínú àwọn onígbàgbọ́ òdodo |