Quran with Yoruba translation - Surah Al-MuTaffifin ayat 13 - المُطَففين - Page - Juz 30
﴿إِذَا تُتۡلَىٰ عَلَيۡهِ ءَايَٰتُنَا قَالَ أَسَٰطِيرُ ٱلۡأَوَّلِينَ ﴾
[المُطَففين: 13]
﴿إذا تتلى عليه آياتنا قال أساطير الأولين﴾ [المُطَففين: 13]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nígbà tí wọ́n bá ń ké àwọn āyah Wa fún un, ó máa wí pé: "Àwọn àkọsílẹ̀ àlọ́ àwọn ẹni àkọ́kọ́ (nìwọ̀nyí) |