Quran with Yoruba translation - Surah Al-MuTaffifin ayat 14 - المُطَففين - Page - Juz 30
﴿كـَلَّاۖ بَلۡۜ رَانَ عَلَىٰ قُلُوبِهِم مَّا كَانُواْ يَكۡسِبُونَ ﴾
[المُطَففين: 14]
﴿كلا بل ران على قلوبهم ما كانوا يكسبون﴾ [المُطَففين: 14]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Rárá kò rí bẹ́ẹ̀, àmọ́ ohun tí wọ́n ń ṣe níṣẹ́ ibi l’ó jọba lórí ọkàn wọn |