Quran with Yoruba translation - Surah Al-MuTaffifin ayat 2 - المُطَففين - Page - Juz 30
﴿ٱلَّذِينَ إِذَا ٱكۡتَالُواْ عَلَى ٱلنَّاسِ يَسۡتَوۡفُونَ ﴾
[المُطَففين: 2]
﴿الذين إذا اكتالوا على الناس يستوفون﴾ [المُطَففين: 2]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni àwọn (òǹtajà) t’ó jẹ́ pé nígbà tí wọ́n bá wọn n̄ǹkan lọ́dọ̀ àwọn ènìyàn, wọ́n á gbà á ní ẹ̀kún |