Quran with Yoruba translation - Surah Ash-Shams ayat 10 - الشَّمس - Page - Juz 30
﴿وَقَدۡ خَابَ مَن دَسَّىٰهَا ﴾
[الشَّمس: 10]
﴿وقد خاب من دساها﴾ [الشَّمس: 10]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ẹnikẹ́ni tí ó bá fi (ìwà ẹ̀ṣẹ̀) ba ẹ̀mí (ara) rẹ̀ jẹ́, ó mà ti pàdánù |