Quran with Yoruba translation - Surah Al-Lail ayat 5 - اللَّيل - Page - Juz 30
﴿فَأَمَّا مَنۡ أَعۡطَىٰ وَٱتَّقَىٰ ﴾
[اللَّيل: 5]
﴿فأما من أعطى واتقى﴾ [اللَّيل: 5]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ní ti ẹni tí ó bá tọrẹ, tí ó sì bẹ̀rù (Allāhu) |