Quran with Yoruba translation - Surah Al-Mursalat ayat 38 - المُرسَلات - Page - Juz 29
﴿هَٰذَا يَوۡمُ ٱلۡفَصۡلِۖ جَمَعۡنَٰكُمۡ وَٱلۡأَوَّلِينَ ﴾
[المُرسَلات: 38]
﴿هذا يوم الفصل جمعناكم والأولين﴾ [المُرسَلات: 38]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Èyí ni ọjọ́ ìpínyà. Àwa yó sì kó ẹ̀yin àti àwọn ẹni àkọ́kọ́ jọ |