Quran with Yoruba translation - Surah Al-Mursalat ayat 41 - المُرسَلات - Page - Juz 29
﴿إِنَّ ٱلۡمُتَّقِينَ فِي ظِلَٰلٖ وَعُيُونٖ ﴾
[المُرسَلات: 41]
﴿إن المتقين في ظلال وعيون﴾ [المُرسَلات: 41]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú àwọn olùbẹ̀rù Allāhu yóò wà níbi ibòji àti àwọn omi ìṣẹ́lẹ̀rú |