Quran with Yoruba translation - Surah Al-Mursalat ayat 46 - المُرسَلات - Page - Juz 29
﴿كُلُواْ وَتَمَتَّعُواْ قَلِيلًا إِنَّكُم مُّجۡرِمُونَ ﴾
[المُرسَلات: 46]
﴿كلوا وتمتعوا قليلا إنكم مجرمون﴾ [المُرسَلات: 46]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ẹ jẹ, kí ẹ sì gbádùn fún ìgbà díẹ̀. Dájúdájú ẹlẹ́ṣẹ̀ ni yín |