Quran with Yoruba translation - Surah Yunus ayat 33 - يُونس - Page - Juz 11
﴿كَذَٰلِكَ حَقَّتۡ كَلِمَتُ رَبِّكَ عَلَى ٱلَّذِينَ فَسَقُوٓاْ أَنَّهُمۡ لَا يُؤۡمِنُونَ ﴾
[يُونس: 33]
﴿كذلك حقت كلمت ربك على الذين فسقوا أنهم لا يؤمنون﴾ [يُونس: 33]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Báyẹn ni ọ̀rọ̀ Olúwa rẹ ṣe wá sí ìmúṣẹ lórí àwọn t’ó ṣèbàjẹ́ pé dájúdájú wọn kò níí gbàgbọ́ |