Quran with Yoruba translation - Surah Yunus ayat 82 - يُونس - Page - Juz 11
﴿وَيُحِقُّ ٱللَّهُ ٱلۡحَقَّ بِكَلِمَٰتِهِۦ وَلَوۡ كَرِهَ ٱلۡمُجۡرِمُونَ ﴾
[يُونس: 82]
﴿ويحق الله الحق بكلماته ولو كره المجرمون﴾ [يُونس: 82]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Allāhu sì máa mú òdodo ṣẹ pẹ̀lú àwọn ọ̀rọ̀ Rẹ̀, àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ ìbáà kórira rẹ̀ |