Quran with Yoruba translation - Surah Yunus ayat 95 - يُونس - Page - Juz 11
﴿وَلَا تَكُونَنَّ مِنَ ٱلَّذِينَ كَذَّبُواْ بِـَٔايَٰتِ ٱللَّهِ فَتَكُونَ مِنَ ٱلۡخَٰسِرِينَ ﴾
[يُونس: 95]
﴿ولا تكونن من الذين كذبوا بآيات الله فتكون من الخاسرين﴾ [يُونس: 95]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni O ò gbọdọ̀ wà lára àwọn t’ó pe àwọn āyah Allāhu nírọ́, nítorí kí o má baà wà lára àwọn ẹni òfò |