Quran with Yoruba translation - Surah At-Takathur ayat 8 - التَّكاثُر - Page - Juz 30
﴿ثُمَّ لَتُسۡـَٔلُنَّ يَوۡمَئِذٍ عَنِ ٱلنَّعِيمِ ﴾
[التَّكاثُر: 8]
﴿ثم لتسألن يومئذ عن النعيم﴾ [التَّكاثُر: 8]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Lẹ́yìn náà, dájúdájú ní ọjọ́ yẹn wọ́n máa bi yín léèrè nípa ìgbádùn (ayé yìí) |