Quran with Yoruba translation - Surah Hud ayat 100 - هُود - Page - Juz 12
﴿ذَٰلِكَ مِنۡ أَنۢبَآءِ ٱلۡقُرَىٰ نَقُصُّهُۥ عَلَيۡكَۖ مِنۡهَا قَآئِمٞ وَحَصِيدٞ ﴾
[هُود: 100]
﴿ذلك من أنباء القرى نقصه عليك منها قائم وحصيد﴾ [هُود: 100]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ìyẹn wà nínú àwọn ìró ìlú tí À ń sọ ìtàn rẹ̀ fún ọ. Ó wà nínú àwọn ìlú náà èyí tí ó sì ń jẹ́ ìlú àti èyí tí ó ti parẹ́ |