Quran with Yoruba translation - Surah Hud ayat 96 - هُود - Page - Juz 12
﴿وَلَقَدۡ أَرۡسَلۡنَا مُوسَىٰ بِـَٔايَٰتِنَا وَسُلۡطَٰنٖ مُّبِينٍ ﴾
[هُود: 96]
﴿ولقد أرسلنا موسى بآياتنا وسلطان مبين﴾ [هُود: 96]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú A fi àwọn àmì Wa àti ẹ̀rí pọ́nńbélé rán (Ànábì) Mūsā |