Quran with Yoruba translation - Surah Hud ayat 95 - هُود - Page - Juz 12
﴿كَأَن لَّمۡ يَغۡنَوۡاْ فِيهَآۗ أَلَا بُعۡدٗا لِّمَدۡيَنَ كَمَا بَعِدَتۡ ثَمُودُ ﴾
[هُود: 95]
﴿كأن لم يغنوا فيها ألا بعدا لمدين كما بعدت ثمود﴾ [هُود: 95]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àfi bí ẹni pé wọn kò gbé inú ìlú náà rí. Gbọ́, ìjìnnà sí ìkẹ́ ń bẹ fún ìran Mọdyan gẹ́gẹ́ bí ìran Thamūd ṣe jìnnà sí ìkẹ́ |