Quran with Yoruba translation - Surah Yusuf ayat 14 - يُوسُف - Page - Juz 12
﴿قَالُواْ لَئِنۡ أَكَلَهُ ٱلذِّئۡبُ وَنَحۡنُ عُصۡبَةٌ إِنَّآ إِذٗا لَّخَٰسِرُونَ ﴾
[يُوسُف: 14]
﴿قالوا لئن أكله الذئب ونحن عصبة إنا إذا لخاسرون﴾ [يُوسُف: 14]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọ́n sọ pé: “Tí ìkokò bá fi pa á jẹ, ọ̀pọ̀ ènìyàn sì ni wá, dájúdájú àwa nígbà náà ni ẹni òfò.” |