Quran with Yoruba translation - Surah Yusuf ayat 27 - يُوسُف - Page - Juz 12
﴿وَإِن كَانَ قَمِيصُهُۥ قُدَّ مِن دُبُرٖ فَكَذَبَتۡ وَهُوَ مِنَ ٱلصَّٰدِقِينَ ﴾
[يُوسُف: 27]
﴿وإن كان قميصه قد من دبر فكذبت وهو من الصادقين﴾ [يُوسُف: 27]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Tí ó bá sì jẹ́ pé wọ́n fa ẹ̀wù rẹ̀ ya lẹ́yìn, (obìnrin yìí) l’ó parọ́, (Yūsuf) sì wà nínú àwọn olódodo |