Quran with Yoruba translation - Surah Yusuf ayat 44 - يُوسُف - Page - Juz 12
﴿قَالُوٓاْ أَضۡغَٰثُ أَحۡلَٰمٖۖ وَمَا نَحۡنُ بِتَأۡوِيلِ ٱلۡأَحۡلَٰمِ بِعَٰلِمِينَ ﴾
[يُوسُف: 44]
﴿قالوا أضغاث أحلام وما نحن بتأويل الأحلام بعالمين﴾ [يُوسُف: 44]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọ́n sọ pé: “Àwọn àlá t’ó lọ́pọ̀ mọ́ra wọn (nìyí). Àti pé àwa kì í ṣe onímọ̀ nípa ìtúmọ̀ àwọn àlá.” |