Quran with Yoruba translation - Surah Yusuf ayat 74 - يُوسُف - Page - Juz 13
﴿قَالُواْ فَمَا جَزَٰٓؤُهُۥٓ إِن كُنتُمۡ كَٰذِبِينَ ﴾
[يُوسُف: 74]
﴿قالوا فما جزاؤه إن كنتم كاذبين﴾ [يُوسُف: 74]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọ́n sọ pé: “Kí ni ẹ̀san (fún ẹni tí) ó jí i, tí (ó bá hàn pé) ẹ̀yin jẹ́ òpùrọ́?” |