Quran with Yoruba translation - Surah Yusuf ayat 98 - يُوسُف - Page - Juz 13
﴿قَالَ سَوۡفَ أَسۡتَغۡفِرُ لَكُمۡ رَبِّيٓۖ إِنَّهُۥ هُوَ ٱلۡغَفُورُ ٱلرَّحِيمُ ﴾
[يُوسُف: 98]
﴿قال سوف أستغفر لكم ربي إنه هو الغفور الرحيم﴾ [يُوسُف: 98]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ó sọ pé: “Láìpẹ́ mo máa tọrọ àforíjìn fun yín lọ́dọ̀ Olúwa mi. Dájúdájú Allāhu, Òun ni Aláforíjìn, Àṣàkẹ́-ọ̀run.” |