Quran with Yoruba translation - Surah Yusuf ayat 97 - يُوسُف - Page - Juz 13
﴿قَالُواْ يَٰٓأَبَانَا ٱسۡتَغۡفِرۡ لَنَا ذُنُوبَنَآ إِنَّا كُنَّا خَٰطِـِٔينَ ﴾
[يُوسُف: 97]
﴿قالوا ياأبانا استغفر لنا ذنوبنا إنا كنا خاطئين﴾ [يُوسُف: 97]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọ́n sọ pé: “Bàbá wa, tọrọ àforíjìn ẹ̀ṣẹ̀ wa fún wa, dájúdájú àwa jẹ́ aláṣìṣe.” |