Quran with Yoruba translation - Surah Al-hijr ayat 45 - الحِجر - Page - Juz 14
﴿إِنَّ ٱلۡمُتَّقِينَ فِي جَنَّٰتٖ وَعُيُونٍ ﴾
[الحِجر: 45]
﴿إن المتقين في جنات وعيون﴾ [الحِجر: 45]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú àwọn olùbẹ̀rù (Allāhu) máa wà nínú àwọn Ọgbà Ìdẹ̀ra pẹ̀lú àwọn odò (t’ó ń ṣàn nísàlẹ̀ rẹ̀) |