Quran with Yoruba translation - Surah Al-hijr ayat 44 - الحِجر - Page - Juz 14
﴿لَهَا سَبۡعَةُ أَبۡوَٰبٖ لِّكُلِّ بَابٖ مِّنۡهُمۡ جُزۡءٞ مَّقۡسُومٌ ﴾
[الحِجر: 44]
﴿لها سبعة أبواب لكل باب منهم جزء مقسوم﴾ [الحِجر: 44]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àwọn ojú ọ̀nà méje ń bẹ fún (iná). Àtúnpín tún wà fún ojú-ọ̀nà kọ̀ọ̀kan |