Quran with Yoruba translation - Surah Al-hijr ayat 64 - الحِجر - Page - Juz 14
﴿وَأَتَيۡنَٰكَ بِٱلۡحَقِّ وَإِنَّا لَصَٰدِقُونَ ﴾ 
[الحِجر: 64]
﴿وأتيناك بالحق وإنا لصادقون﴾ [الحِجر: 64]
| Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni A mú òdodo wá bá ọ ni. Àti pé dájúdájú olódodo ni àwa  |