Quran with Yoruba translation - Surah Al-hijr ayat 82 - الحِجر - Page - Juz 14
﴿وَكَانُواْ يَنۡحِتُونَ مِنَ ٱلۡجِبَالِ بُيُوتًا ءَامِنِينَ ﴾
[الحِجر: 82]
﴿وكانوا ينحتون من الجبال بيوتا آمنين﴾ [الحِجر: 82]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọ́n máa ń gbẹ́ àwọn ilé ìgbé ìfàyàbalẹ̀ sínú àwọn àpáta |