Quran with Yoruba translation - Surah An-Nahl ayat 3 - النَّحل - Page - Juz 14
﴿خَلَقَ ٱلسَّمَٰوَٰتِ وَٱلۡأَرۡضَ بِٱلۡحَقِّۚ تَعَٰلَىٰ عَمَّا يُشۡرِكُونَ ﴾
[النَّحل: 3]
﴿خلق السموات والأرض بالحق تعالى عما يشركون﴾ [النَّحل: 3]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ó ṣẹ̀dá àwọn sánmọ̀ àti ilẹ̀ pẹ̀lú òdodo. Ó ga tayọ n̄ǹkan tí wọ́n ń fi ṣẹbọ sí I |